Are you ready for more?

Ifa, do you not deserve praise? Ifa, you really deserve praise! The life of the Moon is more pleasant than that of the Sun. It does not smart the body, It does not bite the body, Also, it is not painful to the body. -Sacred Odu Ifa Oyeku Ofun

Ifalism theology

ODU IFA IROSUN OPININ

|    |

|    |

||   ||

|    ||

1.IROSUN OPININ——Iku ni yana eepin Arun ni yatunta Ofun ni ya ti omunrunmunr Adifa fun orunmila lojo ti won dana ibi ti baba nita aye kiri ,,,Sorogun mojo awo ile orunmila lodifa fun orunmila woni korubo ko le segun ,opolopo igbin lebo baba gbe ebo orubo won sefa fun ojo nani orunmila segun
2.Igi ajuba lonmi longelonge adifa fun opinin lojo ton sokun wipe oun kodo nigbo Aya won ni korubo osi rubo kope kojina opinin donigbo Aya oun Omo
3.Apirin na abowo dudu Agbe toko bo de ri siosio Olomo see yiya torotoro, Adifa fun orunmila baba nsawo rele aye eleyeye woni korubo osi rubo—:-NJE .. boba sen yemi yio ma yeye nimariwo nye imole yeye
4. Arowo gbuji ogede Adifa fun ininirin eyi tin se Omo olokun lojo ti won loore fi je oye ile baba re ile aye wagun peregede —;-;NJE…Ininirin awo olokun, Omo odo orisa, iwo lafi joye ayegun .
5. Akintude awo ode egba , Aasa awo ode ijesha , Adifa fun porogun susu eyi tin wofa loja loja, oun wofa loba loba, osi nrin lakisa kiri ,bi osen bawon se won ko San oore fun, won iwo porogun susu woni kin se Ara ile niyio la eee ooo, sugbon awo ni yio tunse, kope kojina ni awon awo na ba ko biwon sen sawo,—;- ;NJE.. Akintude awo ode egba ooo ,,Aasa awo mantun awo se oooo Aasa,,,Awo nrele ooo ,,Aasa awo mantun awo se Aasa.
6.Afefelengelenge kofe leleleri Efufuleeleelee lowa gbegba elegbe siporo oko,Awo Ori lodifa fun Ori,Ori ndanun se irahun ire gbogbo , Ori nsen gbogbo nkan ti nkankank Kobo si , ojo yi Ori to awon awo love niyi won ni korubo osi karanile orubo aye Ori wa Dara , kope kojina..ti eni ban wa owo balowo won Oni owo Ori ni. Etc. Ojo ti ori gangan tun wa dawo niyi.leyin na ni Ori wa San olu olu dagba ,Ori San aworo aworo dosu rekete, Ori San bobosigila Ife edun ide lofin lagi, Ori San iponmo oko ikin re po mo osun bo..NJE..Eni ti Ori koba gbe you dabi ebi tiko see obi fun Ori bo.
7. Awodi lapa ofi ese jale, Adifa fun alunkunji Omo orisha lojo ton pelu olokun Jon jijadu agba, alunkunji lo to awon babalawo loo, oun le segun olokun yi lodafa si won ebo ni ki alunkunji o ru osi karanile orubo igba ti yio rubo tan won sefa fun alunkunji safa bi eni sa oogun ,,oun sa Oogun bi eni sa ifa, kope kojina ni ija bere laarin won olokun oun te kini yi ti eni ti kosi nkan kan tomu teletele olokun ba te aso pupa ,, alunkunji na yio so pupa ,,ti OO ba yi dudu alunkunjig na yio yi si dudu ,,ojo ti alunkunji segun niyi ,NJE…Alunkunji ode ooo nisinsin lari oo nigbawo lo pawo da ,Oni elewu ewu laso alagemo.
8. Itanitanisi , ibinibinisi , Adifa fun ikooko eyi tio loree ba olobahun wo ifa odun abufun olobahun eyi tio loree tan ikooko bofa odun ,,besini olobahun ti gbe koto sile fun ikooko owa teni lelori , olobahun wa pe ikooko wa lati wa se ifa odun fun oun ikooko na si tele igba tiwon odele olobahun niki ikooko lojoko sori eni bi ikooko se jasi koto niyi
9. Ori wobi rere gbemide ,Esinsin wobi rere sinmiya bi ako ba debi are aki duro adifa fun sasore eyi tin lore weri elewi danun ,,Awon Ona to taara moya nibi tiwon gbe sunkun ailoba, sasore lon bori elewi lororun ,sasore wa dafa lojokan won ni ki oun bori Ara re woni ire ola, ire oye ,ire gbogbo nbo wafun woni koni (oposi kekere, ogede omini ,oyin ), kofirubo osi karanile orubo
ITAN RE
,ibi ti sasore tin bori re ni elewu ti ranse pee kope kojina ni awon ijoye elewi de, won so fun sasore wipe elewi npe, sasore ni oun bo ori oun lowo ,,inu wan bi awon ijoye elewi ,,won ba lo so fun elewi pe sasore ni oun ti elewi nse koiti to ,,inu na wabi elewi ni ki won lo kan oposi kan kiwon logbe sasore sinu re kiwon lo ju si inu omi ,,,,Awon Ara ode ibinin won kawo mo Ori won yee , won to babalawo lo, awon ona to tarataa moya won ni kan wan rubo won ni oba won wa lori Omi won ni kiwon lo duro si eti omi won ba lo duro sodo tititi to won first oposi loju omi, won ba lo sofun awon babalawo wipe oposi niwon right won o ri eyan ,awon babalawo ni kiwon tu inu posi na ,,igba won o tu posi ni won ba ri sasore, won bamu sasore wafi joba, kope kojina ni elewi ni ki oun waki oba ode ibinin igba to you de odo oba na lowa see sasore to ti Dade Ori oni jawajawa loju woni iwo elewi see o mo sasore ri ni ,,oni benni sugbon sasore tiku tipe tipe, sasore ba sir ok won elewi ,, biki elewi wo ile ni ,kope kojina ni elewi banbe sasore ,,,,sasore ki elewi mase be oun ,,,oni Oro ifa ni oun tell ,,,,,,
REPEAT OLUWO

Advertisements
Create your website at WordPress.com
Get started
search previous next tag category expand menu location phone mail time cart zoom edit close